Home Orisirisi Ká sọ́ra o! Àjálù ibà Lassa pa ènìyàn méjì ní ìlú Èkó
Orisirisi - August 9, 2017

Ká sọ́ra o! Àjálù ibà Lassa pa ènìyàn méjì ní ìlú Èkó

Asiko niyi ki onikaluku le eku jinna ni ile re o, tori ajalu arun Lassa fever ti be sile ni ilu Eko.

Eku lo maa n ko arun naa wo ile, bi o tile je pe kii se gbogbo won lo ni oro buruku naa lara.

Arun naa buru debi pe o fi ara jo Ebola die.

Idi ni pe o le koko debi pe eje maa n jade lara eni to ba mu, ti oun naa si maa n fo fere si ara elomiran.

Bi a se n wi yii, awon alase ile iwosan LUTH, ni Idi Araba ni Eko, so pe arun naa ti fo fere si ara okan lara awon dokita to n wo awon ti o koko mu.

Bee won ti n se ayewo fun ogorun awon osise osibitu naa, ti won ko won jo sibi kan, eyi ti awon oloyinbo n pe ni surveillance.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…