UEFA SUPER CUP: Lukaku ta biobio, sugbon Real Madrid f’agba han Man U
Ayo ti agbaboolu fun Everton tele, Lukaku, gba fun Manchester United ni asale oni ko dara to o, ti a ba wo owo goboi ti won fir a a ati ireti ti awon eniyan ni lori re.
Adura ni awon omoleyin Man U n gba pe ki oro tie naa ma da biii ti Pogba.
Bi o tile je pe o gba boolu wole leekan fun Man U lasiko idije won fun UEFA Super Cup pelu Real Madrid, Lukaku ko ni aseyori to moyan lori.
Bi apeere, o ju boolu kan nu nigba ti o ni anfaani gbayawu lati gba a sinu awon.
Ni igbeyin-gbeyin, Real Madrid ni ami ayo meji, nigba ti Man U ni okan soso.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…