Tontoh Dike n woju Olorun fun igbeyawo miiran
Esin kii da ni ki a ma tun un gun. Bi a ba si ni ki a diju ki eni buruku koja, a ko le mo igba ti eni gidi naa yoo koja lo.
Eyi lo difa fun arabinrin alariya ti a mo si Tonto Dikeh. Aipe yii ni igbeyawo re pelu baale re, Olakunle Churchill, fo yangayanga.
O ti wa so bayii pe oun si silekun okan oun sile, oun si gbokan le Olorun. O ni bi elomiran to ba nifee oun ba wa, oun yoo tun se igbeyawo leekan si i.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…