Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Omo Rashidi Yekini jawe olubori ni Licester city
ERÉ ÌDÁRAYÁ - August 8, 2017

Omo Rashidi Yekini jawe olubori ni Licester city

Okan lara awon omo bibi inu agbaboolu ara fun Nigeria tele, Oloogbe Rashidi Yekini, ti dabira ni ilu Licester, ni orile-ede United Kingdom.

Kii se pe o n gba boolu nibe bii ti Ihenacho tabi Ndidi. Dipo bee, o se bebe ni ile iwe giga ti De Montfort University, nibi to ti di je eni keji to paasi julo laarin gbogbo awon to sese kekoo jade.

Aseyori omobinrin ti oruko re n je Rashidat naa ti mu ki inu opo awon ololufe Yekini maa dunnu, ti won si n sadura fun un, bi won se n sadura fun oloogbe naa pe ki Olorun tubo te e si afefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…