Ko si eni ti a le fi ropo Buhari – Lai Mohammed
…Charley Boy ni ki Aare fipo sile
Minisita fun Oro Iroyin ati Asa, Alhaji Lai Mohammed, ti so fun awon to n se iwode lori ailera Aare Mohammadu Buhari pe ki won tun ero won pa.
Mohammed so lojo Monday pe ko si eni to je pe okuta ni ara re, ti ailera ko le bewo.
O ni Olorun ti n gbakoso lori ailera Buhari. Bakan naa, o ni bo tile je pe Aare ko si nile, ise ijoba si n lo ni pereu.
O ni enikeni to kan n so pe ki Buhari fipo sile kan n pala enu ni. O ni ko si oun to fa eyi.
Lara awon to se iwode pe ki Buhari maa lo ni akorin ti a mo si Charley Boy.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…