Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ìyàwó Tuface ní òun kò ní bímọ mọ́
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 8, 2017

Ìyàwó Tuface ní òun kò ní bímọ mọ́

Iyawo akorin pataki Tuface, iyen Annie Idibia, ti so pe o ti to gee, alubata kii darin.

O ni leyin omo meji ti Olorun ti yonda fun oun lati ara Tuface, oun ko nii bimo mo.

A ko mo boya oun ati oko re ti jo se ipinnu lori eyi sugbon o tenu moo ninu atejade kan pe oun ti dupe lori eyi ti Olorun fun oun.

Leyin omo meji ti Annie bi fun yii, Tuface tun ni omo marun-un miiran lati odo awon obinrin miiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…