Idi ti Foluke Daramola se n pami bi oti – Kayode Salako
O seese ki awon eniyan kan maa ro pe onifiimu ti a mo si Foluke Daramola ti gbe oogun fun oko re, Kayode Salako, je. Eyi da leri bi okunrin naa se maa n gbe e gege nigba kuugba.
Ojoojumo ni won jo n se oko gbegba-n-gbagbon. Nigba ti awon gbajumo kan n yo kuumo ati kondo si iyawo won lojoojumo, ise ni Kayode n fi ife han Foluke nigba kuugba.
Sugbon ti a ba tele ohun ti okunrin naa sese so, ko si ohun to n je oogun ife ninu oro to wa nile yii.
Alagba Kayode ni gbogbo nnkan ni Foluke fi wu oun, to si n te oun lorun pelu iwa ati ewa.
O ni iwe kan n bo lona nibi ti oun ti maa tu keeke oro sile lori nnkan pataki kan ti Foluke fi raga ife boo un patapata.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…