Fayose tun gba ona miiran yo si Buhari
Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, tun ti gba ona miiran yo si Aare Muhammadu Buhari.
Teletele, Fayose so pe aisan to n se Buhari ti da a gunle debi pe ko lee da dide duro mo.
Sugbon awon foto kan to jade lasiko ti awon gomina kan se abewo si i ni London ti fihan pe oro ko ri bi Fayose se ro o.
Bayii, gomina naa ti pahunda.
O ni bi Buhari ba ko ti ko kuro ni ilu oyinbo, ki won kuku so o di Minisita fun Oro Ile Okeere, eyi ti awon oyinbo n pe ni Minister of Foreign Affairs.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…