Home iroyin Àwa mẹ́rìnlélógún ló wà nínú àjà ilẹ̀ báyìí
iroyin - August 8, 2017

Àwa mẹ́rìnlélógún ló wà nínú àjà ilẹ̀ báyìí

Ajaale to wa ni adugbo Ajala ni ipinle Eko ni okan ninu awon meta to jade ninu iho naa ti n ka pe awon merindinlogun lo si wa lenu ise lonii pelu arabinrin kan ti awon fe lo, o tun ni lati odun 2014 ni awon ti bere ise ibi naa, ori arabinrin yii ko gbabode lo je ki ariwo “help! help! re jade sita ti asiri fi tu gege bi awon eniyan to wa nibe se n salaye.

Okan ti owo awon ara ilu koko te je Olorun nipe pelu iku ojiji, won dana sun un ni, eleekeji to tun jade ni nnkan bi aago meji osan ni awon olopaa  ati awon ara ilu n du mo ara won lowo. Awon ara ilu ni didana sun lo le koko te awon lorun.

Ki Eledua maa yo wa ni lowo awon to n so wa ti a ko mo. Gbogbo igbiyanju awon okunrin ati awon ologun to wa nibe lati wo inu iho naa maa ko won jade ni okookan lo ja si pabo, nitori pe awon iho naa kan n jade kaakiri ni. Gbogbo re ri loko-loko, awon onise ibi yii nikan naa lo mo o ona naa rin.

Iyalenu awon ara adugbo naa ni pe, igba wo ni awon eniyan buruku gbe gbogbo iho naa laarin igboro nitori pe adugbo Ajala ko ki n se inu ahere rara.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…