Àjàalẹ̀ ní Àjàlá ti Eko
Iroyin yajo-yajo to te wa lowo laipe yi ni ero repete ni ibudoko Ajala ni opopona Ijaye si Abule-Egba. Ajaale ni won tun ba nibe, nibi ti awon onise-ibi tun ti n ge eya ara omo eniyan sowo. Ile alaja –meji ni ise ibi naa ti n lo lowo. Awon olopaa ti kese bo sokoto kan naa pelu awon onise ibi naa.
Bi o ba se n lo ni IROYIN OWURO maa fi to yin leti. Eledua ko ni je ki a rin arinra o.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…