Ọ̀nà láti ṣẹ́gun Boko Haram – Odumakin
Gbaju-gbaja aja-fun-eto omoniya, Alagba Yinka Odumakin ni o n salaye ona ti Naijiria fi le tete segun awon Boko Haram pata-pata. O ni ija won ko le nira fun awon ologun wa ati pe a ko tile nilo awon jagun-jagun oke okun rara ti a ba se ohun to ye ki a se.
O ni awon ohun to ye ki a se naa ni ki a koko yowo oselu kuro ninu ija naa. O ni gbogbo ogbon ti awon olopolo ba mu wa, ki a koko se amulo re, ki a ma se je ki awon oniroyin maa royin awon ogbon ayinike ti a ba fe lo fun won sita.
Odumakin ni o ye ki a segun awon eni ibi yii tan patapata ki a to maa pariwo sita.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…