Ẹ jọ̀wọ́ o, ta ló bá wa gbúròó Àgbákò?
Olorun ko ni je ki eni kankan wa gburoo agbako. A ko si ni se alabapade re pelu.
Sugbon adura yii kii se bii ti Charles Olumo, akikanju osere ti n je Agbako.
IROYIN OWURO woye pe o to ojo meta ti a ti gburoo osere naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…