Home Orisirisi Dejumo Lewis fẹ́ kí àwọn òǹkọ̀wé máa lo èdè abínibí
Orisirisi - August 7, 2017

Dejumo Lewis fẹ́ kí àwọn òǹkọ̀wé máa lo èdè abínibí

 

Gbajugbaja onifiimu, Alagba Dejumo Lewis, ti gba awon onkowe Naijiria nimoran pe ki won maa lo ede abinibi won lati gbe ise won jade.

O ni bi won ba tie n ko awon iwe kan ni ede oyinbo, ki won maa gbiyanju ko awon kan naa ni ede bii Yn ba n se eyi, ede abinibi naa yoo maa ni idagbasoke ti awon ti ko gbo oyinbo naa yoo si maa ni anfaani lati ka ohun ti won n ko.

Alagba Lewis so eyi ni ilu Eko lojo Sunday nigba ti awon ajo Committee for Relevant Arts gba awon onkowe bii mesan-an kan lalejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…