Home Orisirisi Fanikayode sọ̀rọ̀ kòbákùngbé sí Osinbajo
Orisirisi - August 6, 2017

Fanikayode sọ̀rọ̀ kòbákùngbé sí Osinbajo

Minisita fun Oro Oko Ofurufu tele, Oloye Femi Fanikayode, ti so oro buruku si Adele Aare Orile-ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo.

Fanikayode ni odale ati amotara eni nikan ni.

Ninu leta kan to ko si Osinbajo, o laali igbakeji aare lori iha ti o )Osinbajo) ko si oro atunto Naijiria.

Ti e ko ba gbagbe, Osinbajo so laipe yii pe ko si nnkan kan ti a ni lati tunto lori Naijiria.

Eyi yato si ileri ti APC se nigba ipolongo ibo.

Bee, o lodi si ohun ti awon asiwaju Yoruba n fe.

Fanikayode ni o seni laanu pe Osinbajo se apejuwe awon to n polongo atunto ibo gege bi awon to n wa ipo lati odo ijoba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…