Aago mẹ́rin ìdájí ni mo ti máa ń jí – Buruji Kashamu
Senito kan lati Ipinle Ogun, Oloye Buruji Kashamu, ti so pe aago merin idaji ni oun ti maa n ji lojoojumo.
O ni bi oun ba si ti gbadura, ise oojo ya niyen.
O ni oun koko maa n wo oju foonu oun; o maa n da awon esi pada lori ise afowoko text message ati whatsapp. Leyin eyi ni yoo jeun ko to maa ro bi oun a se jade.
P se alaye oro yii ninu iforowanilenuwo lori bi o se n gbe aye gege bii oloselu nilu Abuja.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…