Home LÁGBO ÀRÍYÁ Orí ló mọ’ṣẹ́ àselà, àsé amòfin ni Aisha Lawal
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 6, 2017

Orí ló mọ’ṣẹ́ àselà, àsé amòfin ni Aisha Lawal

 

Loooto, ori lo mo ise asela o. Opo eniyan to maa n wo Aisha Lawal ninu fiimu Yoruba le maa ro pe boya ko lo si yunifasiti kankan.
Sugbon o ti so fun awon oniroyin pe oro ko ri bee rara.
Koda, yunifasiti aladani lo lo, iyen Leeds City University ni Ibadan.
Ko wa tan sibe o. Eko amofin (Law) ni arabinrin naa ko, ko to di pe ori gbe e lo sidii ise fiimu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…