Olú ilé-isẹ́ àwọn sójà kìlọ̀ fún Fayose
Olu ile-ise awon omo ogun orile-ede yii, iyen Nigerian Army, ti se kilokilo fun Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, lori bi o se n se oselu tie.
Ninu atejade kan, won ni awon ko fara mo oro kan ti gomina so nigba to ni iwa jegudujera wa lowo awon ologun Nigeria.
Won ni Nigerian Army to wa lode yii ko ri bi Fayose se so.
Won wa tenu mo o pe gomina ko gbodo gbe oselu wo bareke awon jagunjagun o.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…