Ikú ìyá Olóbì: Buhari fóònù Aregbesola
Lati ilu Londoonu, ti o ti n gba iwosan, Aare Muhammadu Buhari telifoonu Gomina Ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola, lojo Alamisi, lati ki i ku asehinde iya re to lo sibi agbaa re lojo die seyin.
Aare ni iya daadaa to toju omo ni iya naa ti opo eniyan mo si Iya Olobi ni Ilesa ati agbegbe re.
O wa gba a ni adura pe ki Olorun o fori jin oku, ko si maa fi iso re so awa ti a wa laaye.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…