Home LÁGBO ÀRÍYÁ Banana Fall on Me: Davido ra mọ́tò N33 million naira
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 5, 2017

Banana Fall on Me: Davido ra mọ́tò N33 million naira


Nigba ti akorin hip hop, Davido, ni oun ni owo to to ogbon bilionu naira ninu a-ka-n-ti oun, opo eniyan so pe iro lo n pa. Sugbon awon igbese kan to n gbe lenu loolo yii fihan pe oro naa le ma jinna si otito o.
Leyin awon moto nla nla to wa ninu garaaji re tele, ti G Wagon wa lara won, Davido tun sese ra moto nla Posce miran ni o, eyi ti iye re le ni egberun lona aadorun dola – 90,000 dollars, to si le ni etalelogbon naira – N330 million naira – tii a bam u u wa si owo Naijiria.
Eyi lo fa a ti amoye kan fi so pe, dipo orin Banana Fall on Me ti Davido sese ko, boya Moto Posce Fall on me lo ye ki o maa ko.
Kii se owo ti Davido n ri nidii ise orin nikan lo gboju le. Baba re, Alagba Deji Adeleke je olowo tabua, o kan je pe kii maa n pariwo kiri bi awon olowo miiran ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …