Àhesọ ọ̀rọ̀ kò jẹ́ ká gbádùn mọ́ lórí àpadàbọ̀ Buhari
Paahee ti gba okan opo eniyan lori pipadabo Aare Muhammadu Buhari o.
Lenu ojo meji seyin yii, opo ENIYAN LO N SO AHESO ORO PE Buhari ti de, Buhari ti de.
Awon kan ni baalu re ko si nibi ti won paaki re si mo ni ilu London. Awon kan ni o ti wo ilu Abuja, nigba ti awon kan n so ohun ti eeyan ko gbodo maa so jade.
Bee bi won se n so eyi ni Aare Buhari n gba alejo ni ilu oba.
Lara awon to tun sese se abewo si i ni Oloye Olusegun Obasanjo.
Ohun to fa a ti okan awon eniyan tun se ko soke ni pe o ti to aadorun odun (90 days) ti Aare lo ni ile okeere. Bee, iwe ofin Naijiria (constitution) so pe ti ailera ba ba olori orile-ede fun bii ojo gbooro bayii, awon ile igbimo asofin le seto ki won yo o kuro nipo.
Ipaya kin ni yoo sele, ati pe opo fe ki Buhari tete pada wa sile lati wa gbogun ti awon wahala nla to w anile, lo je ki jinnijinni tubo dab o awon to n soro siwaju ati seyin bee.
Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá?
Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá? E̩ wo fídíò ìsàlè̩ yí, kí e̩ …