Home LÁGBO ÀRÍYÁ   Yegede! Iyabo Oko bori arun stroke
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 3, 2017

  Yegede! Iyabo Oko bori arun stroke

 

Bi e ba ri osere fiimu ti a mo si Iyabo Oko bayii, e le ma tete da a mo. Eni to je pe o sanra pupo tele, to kun laya, to tun kun ni eyin, ti fee di ilepa shandy bayii.
Idi ni pe arun adanigunle ti a mo si stroke ti n ba a ja lati odun to lo.
Sugbon sa o, Olorun ti gbakoso.
Funra Iyabo Oko lo salaye fun awon oniroyin pe oju oun rim obo.
Lopelope awon eniyan, paapaa omo re kan to wa ni ilu oyinbo, ti won n gbe e kaakiri, ti won si toju re, lo fi wa laye.
O ni omo oun naa tun gbe oun lo si orile-ede India, nibi ti oun ti lo osu meje gbako nigba ti oun n gba itoju ni ile iwosan nibe.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…