Ọlọ́run nìkan ló lè gbin ìfẹ́ òdodo s’ọ́kàn ọkọ àti ìyàwó
Odun kanrun-un ti Mosun Filani darapo mo Ogbeni Kayode Oduoye gege bi oko ati aya, igbeyawo re ni opo eniyan fi n gbadura bayii o.
Igbeyawo re ni won fi n se apejuwe bo se ye ki oko ati aya maa gbe.
Lona kinni, bi igbin fa, ikarahun a tele e ni oro Mosun ati baale re.
Bi e ba pe Mosun si aseye kan, oun ati baale re ni a maa ri nibe.
Nigba to wa n soro lori ohun to maa n mu ki igbeyawo o loyin-ladun, o ni owo Olorun ni gbogbo nnkan wa.
Gege bi Filani ti so, Olorun lo maa n gbin ife ati irepo si okan ati aarin awon toko-taya.
Lona keji, ninu iforowero kan pelu kemiashefonlovehaven, o ni ti okunrin ati obinrin ba ti feran ara won, ti won si mo iwa ati ise okookan won, idagbasoke yoo maa ba igbeyawo won.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…