Eré kọ́, àwàdà kọ́, Ronke Oshodi Oke ń sunkún sí oníròyìn lọ́rùn
Lowolowo yii, hilahilo lo joba ni okan osere fiimu ti a mo si Ronke Oshodi Oke.
Koda, woru lo n sunkun bi omode.
Oun to fa eyi ni iforowanilenuwo to se pelu onitelifisan kan to n je Broadway TV.
Nnu iforowanilenuwo naa, won ni Ronke Oshodi Oke so pe oun ko lee ma dana ounje fun okunrin-kokunrin ti ko ba ri owo yo lapo, to ba je pe obinrin ni breadwinner ile won.
Sugbon lati aaro ni Oshodi Oke ti n pariwo pe kii se bi oun se soro naa niyen.
Ere ni opo eniyan koko pe ohun to n so, sugbon nigba ti yoo fi di osan oni, Ronke ti da a si ekun asun-un-dake, to si n logun pe ki awon Broadway TV ba oun tun iforowanilenuwo naa se.
Awon eniyan kan wa n ro pe boya baale re ti n finna mo o ninu ile ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…