Ogun Omode kii sere f’ogun odun: Messi sadura fun Neymar
Owe Yoruba to so pe ogun omode kii sere fun ogun odun, ori papa isere lo ti n sele lowolowo yii o.
O n waye laarin Messi ati Neymar, ti won je eegun leyin ogba fun egbe agbaboolu Barcelona tele.
Neymar ti fi Messi sile si Barcelona. O ti lo si PSG, nibi to ti maa gba 222 million pounds.
Messi so fun Neymar pe inu oun dun pe awon jo pade, o si gbadura fun un pe Olorun yoo se ona re nire.
Neymar naa dupe lowo re. Oun naa si saaro Messi.
O ni, “I will miss you.”
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…