Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ayé sèrántí Fela lẹ́yìn Ogún ọdún
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 2, 2017

Ayé sèrántí Fela lẹ́yìn Ogún ọdún

Fela Anikulapo Kuti di oloogbe ni ogun odun seyin. Awon ololufe re si tun n seranti re. Awon kan ni wolii Olorun ni Fela nitori pe gbogbo ohun to ba ti so lo maa n sele.

Awon kan ni igboya to ni lo je ki awon nifee re, won ni ko ki n beru enikankan, eni naa ki baa je ologun tabi olowo nitori re lo fi ma n korin bi oro ba se ri gan-an. Fela ni iyawo pupo, Eledua si fi awon omo taa lore. Awon kan ni ajafeto omoniyan ni Fela, ni eyi to maa n fi han ninu orin re. Lara awon awo orin Fela ti opo eniyan Feran ni –

Gentleman,Open and close, roforofo, Shakara, Shuffering and Smilling, Unknow Soldier, Why Black Man Dey Suffer, Zombie ati bee bee lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…