Home iroyin Ẹ fura o! Èéfín jẹnẹrétò pa bàbá, ìyá àti ọmọ méjì
iroyin - August 1, 2017

Ẹ fura o! Èéfín jẹnẹrétò pa bàbá, ìyá àti ọmọ méjì

Gbgbo wa ni a gbodo maa gbadura pe ki ohun to sele si ogbeni Ayodele Segun ati iyawo re ma sele si wa o. Lojo Jimoo to lo ni ajalu kan ba oun ati ebi re ni Obajana, ni Ipinle Kogi.
Ninu ile ti won sun si ni eefin jenereto ti fin won ni afinpa.
A gbo pe inu toleeti ni okunrin naa gbe jenereto naa si, ti oun ati awon eniyan re si sun lo.
Lojo keji, okun won ni awon aladugbo won ba ninu ile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…