Home iroyin Iya Rauf Aregbesola di oloogbe
iroyin - August 1, 2017

Iya Rauf Aregbesola di oloogbe

 

Gomina Ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola, ti di omo orukan bayii o.

A gbo pe iya re, Alhaja Saratu Aregbesola, jade laye ni owuro oni.

Gbajugbaja oniowo ni Alhaja Aregbesola nigba to wa laye.

Oni naa ni won yoo sin iya naa ni Ilesa, ni ilana esin Musullumi.

Ki Olorun te iya si afefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…