Home iroyin Iranu abi omiran? Won n ko agbado wo Naijiria lati ile okeere
iroyin - August 1, 2017

Iranu abi omiran? Won n ko agbado wo Naijiria lati ile okeere

 

 

Bi o tile je pe ile oloraa yi Naijiria po, won si n ko agbado wole lati ile okeere o.

Oro yii jeyo lasiko ipade awon gomina ti a mo si Governors Forum, nibi ti won ti soro lori idagbasoke ohun ogbin ati oro aje lapapo.

Minisita fun Oro Ogbin, Oloye Audu Ogbe, ati Minisita fun Oro Isuna, Iyaafin Kemi Adeosun, ni awon ko mo nipa eyi nitori ile ise awon ko fun enikeni ni laisensi lati se bee.

Sugbon okan lara awon to wa ni ipade ni ohun to sele ni pe eni kankan ko nilo lanseesi lati ko agbado wole tori ko si lara awon ti ijoba fi ofin de.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…