Home Orisirisi Audu Ogbe figbe ta: Wọ́n ń ta ọtí Brandy ẹyọ kan ní N500,000 nílùú Abuja!
Orisirisi - August 1, 2017

Audu Ogbe figbe ta: Wọ́n ń ta ọtí Brandy ẹyọ kan ní N500,000 nílùú Abuja!

Minisita fun Oro Ogbin, Oloye Audu Ogbe, ti ke gbajare pe oti brandy kan wa ti won n ta ni Abuja, to je pe iye re le ni egberun lonaa eedegbeta naira (five hundred thousand naira o) o.

Ogbe so oro yii losan-an oni, lasiko apero kan pelu awon gomina.

O ni nnkan buruku naa n sele ni Abuja, to si je pea won olowoogbo tii silekun fun ole naa n ra a.

O ni ohun to ye ki ijoba se ni ki won gbe owo goboi le kiko iru oja bee wole.

Iwadii IROYIN OWURO fihan pea won brandy kan wa to je pe aimoye milionu naira ni won n ta won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…