Àjọ BBOG ní kí ìjọba jọ̀wọ́ dìde ìrànlọ́wọ́ kíákíá
Awon ajo ti kii se ti ijoba,“Bring back our girls” (BBOG) tun ti bere si ni jade bayii nipa awon akekoobinrin Chibok to ku lowo awon Boko Haram. Won ko iwode naa lo si Aso Rock ni Abuja.
Won ni wiwa awon ko da lori omo Chibok nikan, won ni awon tun wa nitori awon oluko Fasiti ti Maiduguri, awon awakusa, ati awon obinrin to n lo sin oku okan ninu won ni ipinle Bornu ti awon ajinigbe tun ko ninu won.
Gbogbo arowa ti adele Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo fi ranse ni won ni ko te awon lorun to, nitori pe awon omo naa ti pe ju ni ahamo awon Boko Haram.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…