Home iroyin Ah! Àáké ni wọ́n fi pa Ọba kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn
iroyin - July 30, 2017

Ah! Àáké ni wọ́n fi pa Ọba kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn

 

Afi ki Olorun Oba funra re gba wa ni orile-ede yii ni o.
Iku ojiji, iku gbigbona ati iku oro ni won fi pa oba alaye kan ni Ipinle Ogun, Alayeluwa Partrick Fasinu, to je Oba Owo, ni agbegbe Yewa.
Ipade lobaloba loti n bo, eyi ti won se ni Ilaro.
Awon alagbapa naa da moto re duro, won wo o jade, won sis a ni asapa pelu aake.
Oro naa buru debi pe won ni won tun jo oku ati moto re guagua.
Awon olopaa Ipinle Ogun n sise lori isele buruku naa lowo.
Bi a ko ba gbagbe, won pa Baale kan naa ni Ipinle Ogun ni nnkan bii odun meji seyin. Bee, awon otookulu miiran naa si ti ku iku gbigbona tele. Ki Olorun ba ni mu owo re ro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…