Wọ́n fẹ́ lé àwọn asẹ́wó kúrò nípínlẹ̀ Ògùn
Ironu nla lo ti de ba opo awon asewo to wa kaakiri nipinle Ogun bayii, won fe le gbogbo won kuro patapata.
Ose meji seyin ni ijoba ipinle Ogun yan igbimo to je pe awon mejo lo wa nibe, awon lo maa sise naa.
Awon igbimo yi ni won mu ninu awon osise ijoba to wa ni Minitry of Youth and Sports ati Ministry of Women Affairs and Social Development.
Gbogbo awon papa isere mereerin to wa ni ipinle Ogun ni won so pe awon asewo naa maa n lo lati fi se ofiisi won, ibe ni ise si ti fee bere bayii.
Papa isere MKO to wa ni Kuto nilu Abeokuta ni won so pe ipade ti won fi yan awon igbimo yi ti waye.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…