Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ọmọ méje ni Ronaldo fẹ́ bí
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 28, 2017

Ọmọ méje ni Ronaldo fẹ́ bí

\
Yoruba bo won ni ohun to wuni nii po lola eni, ologun eru ku, aso re ko ju meji lo.
Bee ni ti oro agbaboolu to gabyi ju lagbaye bayii, Christine Ronaldo. Asiko ti opo awon odo langba n sa fun omo pupo, Ronaldo ni omo meje ni oun fe bi.
Laarin osu bii meloo seyin, omo meta lo wo inu aye re.
Nigba ti obinrin abanibimo kan (surrogate mother) bi ibeji fun un, iyawo re naa tun bi okan, eyi to je ki omo re ti to bii merin.
O ti wa so bayii pe oun ko ni dawo omo bibi duro ti ko ba pe meje.
A ko ri Ronaldo bawi. Owo buruku lo wa lowo re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…