Home Orisirisi ‘Ojú tì í, kọ̀lọ̀bọ́ wọ̀ ọ́’: Aráyé ń fi Fayose se yẹ̀yé lórí ìlera Buhari
Orisirisi - July 27, 2017

‘Ojú tì í, kọ̀lọ̀bọ́ wọ̀ ọ́’: Aráyé ń fi Fayose se yẹ̀yé lórí ìlera Buhari

 

Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, ti di eni ti opo eniyan fi n se yeye bayii o, latari iroyin to sese jade lati ilu London, nibi ti Aare Muhammadu Buhari ti n gba itoju.

Awon foto kan to sese jade, to da lori abewo awon gomina kan si Buhari, fihan pe ara re ti ya daadaa. O le dide naro, o n ba awon alejo re bowo, to si n rerin muse muse.

Eleyii yato si awon ohun ti Fayose ti so tele, nigba to ni Buhari ko le dide naro mo, ati pe ori aga agbede-gbede meji aye pelu orun ni lapalapa wa – ka ma so omiran.

Lojutaye ati lori ero alatagba, won ni ki Fayose so oro miran bayii. Paapaa, awon to je ololufe ati amugbalegbe Buhari n fi gomina naa pa miidin, won n ko orin ‘Oju ti i/ Kolobo wo o fun un’.

 

Ilera Buhari: Won n ko orin ‘Oju tii/ Kolobo wo o’ fun Fanikayode ati Fayose

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…