Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ọgọ́rùn-ún ọdún ó dín díẹ̀ ni bàbá mi lò láyé. Síbẹ̀síbẹ̀, mo sunkún púpọ̀ nígbà tó kú – Afeez Oyetoro
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 27, 2017

Ọgọ́rùn-ún ọdún ó dín díẹ̀ ni bàbá mi lò láyé. Síbẹ̀síbẹ̀, mo sunkún púpọ̀ nígbà tó kú – Afeez Oyetoro

 

Osere komedi pataki, Afeez Oyetoro, ti gbogbo eniyan mo si Saka, ti seranti baba to bi i lomo.

O ni ogorun odun o din die ni baba naa lo laye, sugbon nigba to ku, o n si sunkun-sunkun.

O so eyi lati fi asopo to maa n wa laarin obi ati omo han; ati eyi to maa n wa laarin awon eniyan ati ani to ba niwa rere.

Afeez Oyetoro se arojinle yii nigba to n sedaro Alagba Adebayo Faleti.

O ni loooto, oku agba ni oku baba naa, eyi ti awon Yoruba n pe ni oku eko ati amala.

O ni sugbon, ko si be ko se ni dun awon eniyan die, tori ohun ribiribi ti baba naa gbaye se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…