Home iroyin Àtúntò nípa ìwé òfin Nàìjíríà ń kọ ará ìlú lóminú
iroyin - July 27, 2017

Àtúntò nípa ìwé òfin Nàìjíríà ń kọ ará ìlú lóminú

Eto nipa atunto opo nnkan ni Naijiria bere lodo awon ile igbimo asofin wa gbogbo ni ose yii. Owo ti awon Asofin yii fi mu atunto naa n ko awon ara ilu lominu. Awon eniyan ni bi o tile je pe won ko tii pari sugbon iwonba ti awon n feti ko ninu re n ko awon lominu.

Awon ara ilu ni o dabi igba ti awon eniyan yii n kan n roko si odo ara won lasan ni.Ara won ni Agbejoro agba to maa n ja fun eto omoniyan Jiti Ogunye, O ni oro atunto kuro ni ki a kan dede paaro oruko lasan, bi apeere “ Nigeria Police force maa di Nigeria Police”.

Awon kan ni nitori pe Aare Buhari ko si nile maa je ki won ko iyan tire lai fi ewe boo. Won ni awon ko rii gbo, ibi ti agbara Aare ti po sii. Awon ara ilu tun ni ko ye ki won din agbara ajo to n foju to awon to n ko owo ilu je ri mobo ku rara, iyen EFCC. Won ni se lo ye ki agbara won tun po sii ti a ba fe finnu-findo gbogun ti iwa ikowoje.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…