Home iroyin Ọkùnrin tó sọ ajá rẹ̀ ní Buhari ja ogun àjàyè
iroyin - July 26, 2017

Ọkùnrin tó sọ ajá rẹ̀ ní Buhari ja ogun àjàyè

Ni bayii, o jo pe oruko to ba wu eniyan lo le so aja, ewure tabi agutan to ba n sin o.
Bo ba wu u, o le fun ni oruko oba ilu kan, o le fun un ni ti gomina, o si le fun taja-teran re ni oruko olowo tabua kan.
Ohun to mu ero yii wa ni idajo kan to waye lojo Isegun, nibi ti Adajo O. O. Adebo ti tu okunrin kan to so aja re ni Buhari, iyen Joachim Iroko, sile pe ko maa lo ile re ni alaafia.
Awuyewuye nla lo be sile nigba ti Iroko sese so aja re ni Buhari Eyi lo mu ki awon olopaa gba a mu, ti won sig be e lo sile ejo.
Sugbon abalobabo ibe ni pe adajo ni awon agbofinro kuna lati so idi ti oun fi gbodo fiya je okunrin naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…