Mọ̀lẹ́bí Faleti lọ se àbẹ̀wò sí Aláàfin, osù kẹsàn-án ni wọ́n yóò sin òkú
Awon molebi agba alariya ati agbasaga to papoda, Alagba Adebayo Faleti, ti se abewo pataki kan si ilu Oyo, nibi ti won ti lo tufo re fn Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi.
Won se eyi nitori pe omo ilu Oyo ni Faleti, to si je pe omo oba ni, tori idile oba lo ti wa.
Okan ninu awon omo re, ti oruko re n je Gbemisola, se alaye pe, ni ile Yoruba, bi won se maa n tufo eni to ba wa ni idile oba niyen.
O wa fi kun un pe inu osu kesan-an odun ni won yoo sin gbajugbaja osere naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…