Home Orisirisi Soyinka sọ àsírí àseyorí Fálétí
Orisirisi - July 25, 2017

Soyinka sọ àsírí àseyorí Fálétí


Igilanko onkowe, to tun je akoko Nobel laureate ni ile Alawo Dudu, Ojogbon Wole Soyinka, naa ti sedaro oloogbe Adebayo Faleti o.
Soyinka ni opomulero asa ati imo ni Faleti je, to si fie bun ti Olorun fun fa agbega fun ominiyan.
O wa se alaye idi re to fi je pe Faleti ni aseyori ninu gbogbo ohun to se. Soyinka ni o je eni kan ti kii se gabagebe. O ni Faleti kii se igberaga rara, bo tile je pe o ni imo ijinle pupo.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…