Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ronaldo ní òun kò ní kúrò ní Real Madrid
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 25, 2017

Ronaldo ní òun kò ní kúrò ní Real Madrid

Agbaboolu to gabyi ju lagbaye lowolowo yii, iyen World Footballer of the Year, Christine Ronaldo, ti fi okan awon ololufe Real Madrid bale o, o ni oun si wa pelu won timotimo bi eti see mori.

Opo eniyan lo ti n ro pe Ronaldo fe salo si ibo miran, paapaa nigba ti won fie sun kan an pe o se magomago owo ori sisan.

Sugbon o ti so bayii pe oun ko ni yese.

O ni oun fe tubo mu ola ati ogo ba Real Madrid ati ara oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…