Ìwọ́de àwọn ọ̀dọ́ nílé ìgbìmọ asòfin l’Abuja
Oni ojo Tuside ni awon odo kan ti won n ja fun eto awon ewe ti won pe oruko ara won ni “I support #Nattoo Young to run movement” se iwode woorowo lo si ile igbimo asofin ni Abuja.
Won ni aseju awon agbalagba ti po ju, ki ile igbimo sofin to maa fun awon odo naa laaye lati dari ilu yii die.
Bi o tile je pe awon agbofinro ko je ki won wole sugbon won papa je ki araye mo ero inu won ki won to fi agbegbe naa sile.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…