Home iroyin FRSC fẹ́ bẹ̀rẹ̀ rédíò òpópónà
iroyin - July 25, 2017

FRSC fẹ́ bẹ̀rẹ̀ rédíò òpópónà

Oga agba kan ni ileese awon eso oju ona “Federal Road Safety Corps”, Ogbeni Boboye Oyeyemi ni o n ba ileese iroyin ile wa to fikale soke okun “News Agency of Nigeria to wa ni New York” soro pe Naijiria naa ko ni pe bere Redio opopona, Redio yii ni o maa salaye bi ona se ri, ibi ti o see gba, ibi ti ko see gba ati awon nnkan miran to ba oju ona mu.

O ni gbogbo awon orileede to ti ni idagba soke lo ni tiwon. O ni eyi tun maa din inawo ijoba apapo kun lori owo goboi ti awon fi maa n se ikede lori redio ati Telifison.

Oyeyemi ni bayii gan-an, ijoba apapo ti fase sii fun awon ipinle merindinlogun lati bere redio opopona tiwon. Oyeyemi ni ikede maa waye lori redio ti awon ni gbogbo ogbon iseju fun anfani awon ara ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…