Ebi góòlù ń pa Lukaku
Golikipa to ba se monamona niwaju Romelu Lukaku ni odun yii, yoo da ara re lebi. Idi nip e ebi goolu n pa agbaboolu naa bi ebi aja se maa n pa Ogun Lakaaye.
O ni bi oun se darapo mo Man United bayii, iduro ko si, ibere ko si ni fun oun – iroko to wo sile agbedo.
Lukaku ni oun fe ni rekoodu ti Ronaldo ni ni Man U, leyii ti kii se wasa rara.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…