Home iroyin Àwọn gómìnà méje ń sàbẹ̀wò sí Buhari
iroyin - July 25, 2017

Àwọn gómìnà méje ń sàbẹ̀wò sí Buhari

Awon agbegbe oloselu mefeefa ni asoju gomina ti jade lati be Aare wo. Abdulaziz Yari ti se gomina ipinle Zanfara to tun je olori gomina ni Naijiria ni o maa saaju iko naa. Awon gomina mefa to ku ni – Dave Umahi ti Ebonyi, Umar Ganduje ti Kano, Samuel Ortom ti Benue, Udom Emmanuel ti Akwa Ibon ati Abiola Ajimobi ti Oyo.

Gege bi alaale eto naa, ale oni ni won maa gbera, won si maa de ilu London ni aago meta ojo Weside. Awon oniroyin tun towo bo Garba Sheu ati  Femi Adesina ti won je olubani-damoran agba lori eto iroyin ati etigbo lenu nipa gomina ipinle Ekiti, Ayodele Fayose. Won ni kin lo de ti ijoba ko yan an lati lo sibi abewo naa. Garba ni awon ko ni awon yan awon gomina naa, awon kan mo sii ni, awon ko si lase lati so pe ki enikan lo tabi ki enikan ma se lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…