Home iroyin Olùkọ́ rí ìyà he lọ́wọ́ òbí tó nan ọmọ rẹ̀
iroyin - July 24, 2017

Olùkọ́ rí ìyà he lọ́wọ́ òbí tó nan ọmọ rẹ̀

Arabinrin Ayinde ni o ko awon toogi lo nan Ogbeni Monsuru Kusimo ti ileewe Saje High ni Abeokuta. Gbogbo awon oluko bii mefa ti won fe gba Ogbeni Monsuru sile lowo awon janduku naa ni won je ajekun iya ni ojo naa.

Ogunjo osu yii naa ni isele naa sele nigba ti Ogbeni Monsuru fi egba nan omo naa. Oro naa di oro ileejo, Adajo Arabinrin Adeola Adelaja gba iduro arabinrin omo ogoji odun naa pelu egberun lona igba (N200,00) ati awon oniduro. Adajo ni Arabinrin Ayinde jebi esun meta – Ida alaafia ilu ru, fifi abuku kan eniyan ati didi ipanpa po lati fiya je eeyan. Ile ejo si sun igbejo si ojo kejilelogun, osu kejo odun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…