Ó se, òsèré Yorùbá míràn tún kú lónìí!
Leyin ojo kan pere ti Alagba Adebayo Faleti je Olorun nipe, Yoruba tun ti padanu osere tiata miran o.
Oluware ni Olurotimi Josiah Ayinde, ti adape re n je Abu Olododo.
A gbo pe osere miran, Waheed Ijaduola, ti se idaro iku okunrin naa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…