Ikú Fálétí ba Túndé Kèlání lẹ́rù lórí ìràpadà àṣà Yorùbá
Onifiimu to gbaju-gbaja, Tunde Kelani, naa ti sedaro Alagba Adebayo Faleti.
O ni iku re da bii odidi ile isenbaye ba da wo lule tabi to ba jona guagua.
Ohun to mu Kelani so bee ni pe Faleti ni imo ijinle asa ati ise Yoruba, o mo itan, o mo ede, o si tun je eni to lebun ati gbe awon asa ati ise naa ga.
O ni ti iru awon eniyan ba n ku lawujo, o ye ki ominu maa ko awon to ku leyin.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…