Home iroyin Àríyànjiyàn lórí ọjọ́ tí wọ́n bí Fálétí
iroyin - July 24, 2017

Àríyànjiyàn lórí ọjọ́ tí wọ́n bí Fálétí

Bi o tile je pe opo eniyan si n sedaro agba oje onifiimu to re ibi agba a re lojo Sunday, ariyanjiyan ranpe ti waye lori ojo ti won bi i ati iye odun to lo laye.
Opo awon oniroyin lo so pe eni odun merindinlaadorun (86 years) ni. Sugbon awon molebi re ni odun marundinlogorun (95 years) lo lo laye.
Ohun to ru awon eniyan die loju ni pe agba osere naa ko darugbo kujokujo bi opo eni to ba fee to ogorun odun se maa n ri.
Sugbon sa o, a ko le mo iya Oso ju Oso lo. Ki Olorun te e si afefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…