Alàgbà Fálétí fẹ́ràn Nàìjíríà dọ́kàn – Lai Mohammed
Minisita fun Oro Iroyin ati Asa, Alhaji Lai Mohammed, naa ti soro lori iku agba onkowe, osere ati ogbifo, Alagba Adebayo Faleti.
O ni onimo ijinle ati oluferan asa ati ise ti ko legbe ni.
Mohammed ni Faleti lo igbesi aye rere nipa lilo ebun ti Olorun fun un lati gbe ogo Yoruba, Naijiria ati ile alawo dudu ga.
O ni leyin pe o se gudugudu meje ati yaaya mefa fun ise alariya, o tun je eni kan to feran Naijiria gidi, to si maa n se ko le goke agba.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…