Home iroyin A kò lè rírú Adébáyọ̀ Fálétí mọ́ – Femi Osofisan
iroyin - July 24, 2017

A kò lè rírú Adébáyọ̀ Fálétí mọ́ – Femi Osofisan

 

Onkowo pataki, Ojogbon Femi Osofisan, ti so pe, adura ko, epe ko, a ko le riru Adebayo Faleti mo.

Osofisan ni oloogbe naa dabi opa pataki to gbe ogo Yoruba duro. O ni ko si iru eniyan bee mo laarin awon odo langba. O wa woye pe ti a bar o pe iru Faleti tun le waye mo, ibo lo fe gba wa?

O ni ti awon eniyan ba n sedaro osere naa, kii se tori pe ko dagba to ko to ku, bi ko seese ki iru re tun waye mo lo n ko won lominu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…